"kaka k'eku ma je sese,yio ha fi se awada ni" Femi Fani Kayode lo so be



Latari rogbodinyan ti ijoba apapo nba agbejo agba fun orilede Nigeria Justice Walter Onnoghen fa, Minisita nigbakanri Femi Fani Kayode ninu atejade kan to se lori ero ayelujara facebuku re. 

O fi ibanuje ran han nipa iwa aibikita, iwa jegudujera ati iwa iyanije ti ijoba apapo labe eto idari Muhamadu Buhari ti pinu lati lo, lati fi yo Adajo agba na lenu ise ni ona ti ko ba ofin orilede Nigeria mu.

Comments