Ibanuje dori agbakodo nigba ti oko isele ijamba oko kan sele ninu oja Oshodi. Arabirin oloja kan ton ta omi ni egbe titi ni oko ajagbe kan ya pa tomo-tomo.
Awon ti oro na se oju won so wipe, awako ajagbe na lo se asise, ti o si lo fi tire koba arabirin na ati omo re. Awon eleyinju anu to wa ninu oja na wa pe awon awon eleso abo ilu ati agbofinro, ti won si gbe oku awon ologbe mejeji na lo si ile igbokusi kan to wa ni ipinle Eko.
Comments
Post a Comment