Isele ijamba oko kan eyi to waye ni agbegbe Sandringham ni orilede London ni ori ti ko omo oba Philip yo.
Gege bi iroyin to to wa leti, omo oba na eni to je omo odun merindinlogorun lo gbiyanju lati wa oko re si eba ona, ti oko kan ton sare asapajude bo si gba oko na.
Adupe wipe omo oba na ko farapa, o si ti wa ni alafia to peye.

Comments
Post a Comment