Keere O! Ajo INEC ti sun eto idibo siwaju


Ajo ton mojuto eto idibo ni orilede Nigeria Independent National Electoral Commission, INEC, ti se ikede ati atejade kan lati fi han wipe won ti sun eto idibo to ye ko waye loni ojo kerindinlogun osu keji odun 2019 siwaju si ojo ketalelogun osu keji odun 2019.

Oga agba ajo na Ojogbon . Mahmood Yakubu lo se ikede ati afihan na leyin opolopo wakati ipade pelu awon akegebe re.






Comments