Iyalenu nla lo je nigbati irohin wipe Alhaji Sani Inuwa Nguru eni to je alagba ati agba ninu egbe oloselu PDP ni ipinle Yobe ti kuro ninu egbe na bo si inu egbe oloselu APC paapa julo nigba ti eto idibo fun ipo Aare ku ojo meji pere.
Alaga egbe oloselu APC, Dokita. Mohammed Abuza lo mu Alhaji Sani Inuwa Nguru lo se ipade ranpe pelu Aare Muhammadu Buhari nibe si ni Nguru ti fi idi re mule wipe oun ti setan lati ba egbe oloselu APC sise takun-takun ninu eto idibo ton bo lona.

Comments
Post a Comment