Gege bi atejade ti ile ise irohun Aljazeera se lori ikanle ayelujara won, won fi han wipe awon agbebon kan ti won da aso dudu boju ti ji ogbeni Buba Galadima, eni to je okan gboogi lara awon ton tako ise ijoba egbe oloselu APC ati Aare Buhari gbe.
Agbenuso fun egbe oloselu PDP, ogbeni Kola Ologbondiya na se atejade kan lori ero ayelujara twitter ati facebuku re lati le fi idi oro na mule.
Awon agbofinro ati eleso abo ilu ti wa bere iwadi to peye lori oro na, won si ti se ileri wipe laipe-lai jina, ooto oro na yo jade sita.
Comments
Post a Comment