Ogbeni Alowonle Asekun, akapo egbe NURTW ti agbegbe Jibowu si Yaba ni irohin fi to wa leti wipe awon agbebon kan ti yin ibon pa ni iwaju eleko girama kan ni Ikorodu.
Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe awon arakunrin merin kan lo dode Alowinle ni agbegbe Ajasa-Lamberu ni nkan bi ago meji osan ti won si yin ibon ppa arakunrin na ni kete ti won ri to jade kuro ninu ile re.
Leyin igba ti won yin ibon pa ni won yo ero ibanisoro re, ago ati owo apo re, ti won si fi oku re sile fun awon agbofinro lati wa gbe. Iwadi to peye ti wa bere lori oro na, awon agbofinro si ti pinu lati mu awon odaran na.

Comments
Post a Comment