Aworan Aare Muhamadu Buhari ninu oko re to wa ni ilu Daura



Aare Buhari loni lo se afihan awon aworan yi ninu oko re to wa ni ilu Daura olu-ilu Katsina lori ero ayelujara twitter re, leyin eto idibo to waye ni ana ojo abameta.

O se atejade kan na lati fi han wipe oun ti pinu lati gbe eto ise agbe ati nkan osin laruge ti oun ba pada wole gege bi Aare orilede Nigeria fun igba keji.

Comments