Arabirin Bisi Silva, oludasile ile ise Artistic Director of the Centre for Contemporary Art (CCA) ati aburo gbajugbaja oserebirin Joke Silva ti ku leyin to ba aisan jejere ja ijakadi.
Iwadi fi ye wa wipe nkan bi ago meta abo osan ni arabirin na ku ni ile iwosan kan ni ipinle EKO.
Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire, ko si tu awon molebi ati ore ologbe na ninu. Amin.

Comments
Post a Comment