Egbe agbaboolu Arsenal ti fi agba han egbe agbaboolu Southampton pelu omi ayo meji si odo (2-0)

Idije ifesewonse to waye laarin iko egbe agbaboolu Arsenal ati akegbe won Southampton ninu idije English Premier Leauge ni egbe agbaboolu Arsenal ti ko egbe agbaboolu Southampton leko, ti won si fi ajulo han won nigba ti won na won ni omi ayo mejisi odo.

Agbaboolu Alexandre Lacazette lo koko gba omi ayo kini wole ni nkan bi iseju kefa ti idije na bere, ti akegbe re Henrikh Mkhitaryan si gba omi ayo keji na wole ni nkan bi iseju ketadinlogun.

Comments