Egbe agbaboolu PSG ti fi agba han egbe agbaboolu Man-Utd nigba ti won na won ni omi ayo meji si odo (2-0)

Idije ifesewonse to waye laarin iko egbe agbaboolu PSG ati akegbe won Man-Utd lo ja si omi ayo meji si odo nigbati egbe agbaboolu PSG fi enu Man-Utd gbole.

Ogbeni Presnel Kimpembe lo koko gba omi ayo kan wole fun PSG, ti KYLIAN Mbappe si gba omi ayo keji wole. Egbe agbaboolu Man-utd gbiyanju titi lati ri omi ayo kan dapada sugbon pabo lo ja si.

Ogbeni Paul Pogba bakana ni won le jade kuro ninu idije na fun igbakugba to ba egbe agbaboolu PSG gba.

Comments