Ikede pataki lati enu Aare Buhari ni dede ago meje aro oni. E teti le ko!

Gege bi atejade ti agbenuso fun Aare orilede Nigeria ogbeni Femi Adesina se lori itakun ayelujara twitter re, o fi han wipe Aare Buhari ni ikede pataki kan fun gbogbo awon omo orilede Nigeria ni dede ago meje aro kutu-kutu oni.

E teti le ko.

Comments