Ile ejo ti fi Babachir Lawal si atimole awon osise ajo EFCC

Ile ejo agba kan to wa ni ilu Abuja ti sun igbejo ogbeni Babachir Lawal siwaju si, ti won si ti pase fun ajo EFCC lati fi si atimole. 

Ajo Efcc lo fi esun jibiti kan arakunrin na, ti igbejo na yo si waye ni ola ojo ketala osu kejiodun yi.

Comments