Ninu atejade kan ti agbenuso fun ijoba orilede China ogbeni Geng Shuang se nigba to se abewo si Aare Muhamaadu Buhari ni ile ijoba to wa ni ilu Abuja lori eto idibo ton bo lona, o fi han wipe digbi-digbi ni ijoba orilede China wa leyin orilede Nigeria lori eto isejoba ati eto idibo orilede na.
O so siwaju si wipe gbogbo nkan ti orilede China ba ni ni ikawo won lati ran orilede Nigeria lowo lati ri wipe irorun de ba igbayegbepo awon mekunu to wa ni orilede yi, ni awon o gbiyanju lati se.
Aare Buhari ki ku akitiyan, o si dupe lowo orilede China lapapo fun ife ati ifowosowopo won ojojumo.

Comments
Post a Comment