Ojo gbogbo ni t'ole, ojo kan ni ti oloun ni oro Spirit ogbontarigi onijibiti kan nigba ti owo awon agbofinro ba ni ipinle Katsina.
Agbenuso fun awon olopa ni ipinle Katsina SP Isah Gambo nigba ton ba awon agbofinro soro fi idi oro na mule, o si salaye siwaju si wipe arakunrin Auwal Musa lati Bachirawa ni ipinle Kano ni awon osise ile ise olopa mu nigba ton gbiyanju lati fi ona alumokoroyi gba owo lowo arakunrin Zaharadeen Lawal ni ipinle Katsina.
Arakunrin Lawal lo so wipe Auwal (Spirit) lo ti gba opolopo owo lowo oun latari wipe oun fe ba se ogun iwure ti yo mu ki orire ma tele kakiri. Ogun Spirit lo sunko nigba ti owo palaba re segi, ti awon agbofinro mu si atimole.

Comments
Post a Comment