Awon eyan mẹ́tàdínlọgọ́jọ lo ti so emi won nu ninu baalu to ja ni orilede Kenya



Ibanuje nla lo je nigba ti irohin ijamba oko ofurufu Ethiopian Airlines Boeing 737 ja ti awon eyan to to mẹ́tàdínlọgọ́jọ  si so emi won nu nigba ti won lo si orilede Kenya.

Baalu na ni iwadi fi ye wa wipe won sese ra ni nkan bi osu merin seyin, idi isele buruku yi lo si je kayefi fun gbogbo eyan.

Aare orilede Ethiopia  Abiy Ahmed ninu atejade kan to se ti fi idi irohin na mule, o si so siwaju wipe iwadi tin lo lori isele na.

Comments