Awon olode kan ti gba oga olopa kan lowo awon ajinigbe ni ipinle Rivers

 Gege bi atejade kan ti ogbeni  Ross Alabo-George se lori ero ayelujara facebook, o fi han wipe owo palaba awon ajinigbe kan segi nigba ti awon olode adugbo gbiyanju lati dola emi oga olopa kan to wa ni igbekun awon ajinigbe na.

Iwadi to peye ti wa bere lori oro na, won si ti pinu lati mu awon ajinigbe na lo lati foju ba ile ejo.



Comments