Egbe agbaboolu Man-U ti fi agba han akegbe won PSG nigba ti won na won ni omi ayo meta si okan (3-1)

Idije ifesewonse to waye laarin egbe agbaboolu Man-U ati PSG ninu idije Champions league ni egbe agbaboolu Man-U ti  na iko egbe agbaboolu PSG ni omi ayo meta si okan lati gbe igba oroke.

Romelu Lukaku lo gba omi ayo meji wole fun Man-U ti Marcus Rashford si gba eyokan wole lati fi oba le. 
Wayi, agbaboolu Juan Bernat Velasco  gba eyo kan wole fun PSG sugbon o se wipe epa o ba oro mo.

Comments