Gbajugbaja oserebirin Seyi Ashekun ti bi omobirin lanti-lanti

Gbajugbaja oserebirin Seyi Ashekun ninu atejade kan to se lori ero ayelujara instagram ti fi han wipe Olorun ti fun oun ni omobirin tuntun lanti-lanti.

O fi aworan yi han nibi to ti gbe omo re dani ni ile iwosan kan ni ilu America.

Comments