Awon omo egbe ile igbimo asofin ti fi owo si abadofin lati fi owo kun owo osu awon osise ijoba.
Won ti so owo na di ogbon-egberun naira. Senito Francis Alimikhena nigba lo gbe aba na jade ti awon akegbe re si fowosi.
Aare ile igbimo asofin Senito Bukola Saraki bakana fi ounte gun aba na o si se atejade kan lati fi idi re mule.
Atejade na ni yi ni ede geesi;

''Let me join our colleagues to commend the efforts of the committee. More importantly, let me commend the patience of Nigerian workers and the leadership of the Labour Union, who have over the years been calling for this minimum wage and have carried their efforts responsibly.
I want to commend the leaders of the organisations of the union. Let me also state that as government, we should ensure that at times like these, we should not wait for there to be strikes to do what is truly deserving for our workers. I hope that with this minimum wage our workers will double their efforts to increase their productivity, so that we can also improve the general productivity of the country. It is my hope that the implementation of this will start immediately''.
Comments
Post a Comment