Jimi Agbaje oludije fun ipo Gomina ipinle Eko labe egbe oloselu PDP ki akegbe re labe egbe oloselu APC Babajide Sanwolu ku orire
Ninu atejade ati afihan awon aworan kan ti Gomina ipinle Eku tuntun ogbeni Babajide Sanwolu se lori ero ayelujara Twitter re lo fi han wipe akegbe re labe egbe oloselu PDP ti pe oun lori ero alagbeka to si ti ki oun ku orire.
O fi idun re han, o si dupe lowo ogbeni Jimi Agbaje fun ife ati ifomaniyan se to fi han lori abajade eto idibo na.
O fi idun re han, o si dupe lowo ogbeni Jimi Agbaje fun ife ati ifomaniyan se to fi han lori abajade eto idibo na.
Comments
Post a Comment