Ijamba oko kan to waye ni ilu Sokoto ni akekobirin kan ti oruko re nje Sanusi Muraina Adamu ti so emi re nu.
Gege bi atejade ati iwadi, ologbe Murina lon pada lo si ile iwe re lati lo pari idanwo asekagba ti o si se alabapade iku aitojo ninu ijamba oko na.
Adura wa ni wipe ki Olorun foriji ologbe na, ko si fun awon molebi re ni agbara lati gba kadara. Amin.

Comments
Post a Comment