Oserekunrin Tony Anyasador ti ku

Ibanuje nla lo je nigba ti irohin iku oserekunrin Tony Anyasador to wa leti. 

Iwadi fi han wipe arokutu-kutu ojo keje osu keta ni oserekunrin na dagbere faye leyin to ti ba aisan ja ijakadi ni ile iwosan ijoba to wa ni ipinle Imo.

Awon ololufe ati molebi re ti gbe oku re lo si ite igboku si. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments