Oludije labe egbe oloselu APC ninu eto idibo Gomina to waye ni ipinle Kwara Abdulrahman Abdulrazaq lo gbegba oroke.
Ajo INEC nigba ti won se akojopo ati abaje awon ibo na lo se atejade itangbagba ti won si fi idi re mule wipe egbe oloselu APC lo gbegba oroke.
#OTOGE
Comments
Post a Comment