Aare Buhari se ipade pajawiri pelu awon eleso abo ilu



Aare Buhari lonise ipade pajawiri pelu awon aga agba eleso abo ilu. Ninu ipade na, o pase fun won lati mojuto eto oro abo ilu to tin fidi remi, o si gba won ni iyanju lati se awon odaran ti owo ba ba bi ose se n se oju.

Ipade yi waye ni ile Aare to wa ni Aso Villa ni ilu Abuja. Ogagun Gabriel Olonisakin ati oga olopa Mohammed Adamu nigba ti won ba awon oni rohin soro fi idi oro na mule paapa julo leyin ti ipade na pari.

Comments