Ajo ASSU ton soju ekun ijoba ipinle Taraba ti fi han wipe awon ti gunle eto iyanselodi ni perewu.
Alaga egbe na dokita Samuel shikka ati akowe egbe na nigba ti won ba awon akorohin soro so wipe ijoba apapo ti ko lati mu adehun won se lori ileri ti won se ni odun 2018 lati san gbogbo owo awon osise ti won je. Eleyi lo fa ti ajo na fi fenuko lati gun le eto iyanse lodi yi titi di igbati ijoba apapo o fi mu ileri won se.
Awon akeko wayi ti wa na owo ebe si ijoba apapo lati gbiyanju ki won si da ajo ASSU lohun ibere won nitoriwipe awon akeko ni won faragba eto iyanselodi yi ju.

Comments
Post a Comment