O kere tan awon eyan mẹ́rìndínlọgọ́jọ lo ti so emi won nu ninu ikolu ado oloro kan to dun ni ile ijosin awon kristeni to wa ni orilede Sri Lanka.
Ikolu na waye ni awon ile ijosin to wa ni agbegbe Colombo, Negombo, Batticaloa ni ayajo ojo ajinde Jesu. Aare orilede na ti fi enu ate ba ikolu na, to si ti pase fun awon agbofinro lati wadi finifini nipa awon to dan iru iwa ika na wo.
Comments
Post a Comment