Awon eyan mokandinlogun lo ti ku ti opolpopo awon miran si farapa ninu ijamba oko kan to waye ni ipinle Katsina
Ijamba oko buruku kan waye ni oju opopona Daudawa si Funtua ni ijoba ipinle Faskari to wa ni ipinle Katsina. Awon eyan mokandinlogun o kere tan lo ti so emi won nu ti opolopo awon miran si farapa yana-yana.
Oga agba ajo eleso abo oju opopona FRSC, ogbeni Godwin Ngeuku fi idi oro yi mule nigba ton ba awon akoroyin soro. O so siwaju si wipe ere asapajude awako ayokele kan lo fa idi ijamba na nigbati oko ayokele na takiti si odi keji ti o si pa awon to wa ninu oko na lesekese.
Won ti gbe awon to so emi won nu ninu ijamba oko na lo si ite igboku si to wa ni ipinle le, awon to si farapa si tin gba itoju to peye ni ile iwosan ijoba ni ipinle na bakana.

Comments
Post a Comment