Ewo ni Irun dada ati aworan ara ninu asa ati ise wa- Oga Olopa Bala Elkana lo so be

Ninu iforojomitioro-oro to waye laarin oga agba awon olopa ni ipinle Eko Bala Elkana ati ile ise irohin BBC Pidgin, Oga olopa na so wipe iwa ika gba ni bi awon olopa meji kan se yin ibon pa ogbeni Kolade Johnson, o si fi idi re mule wipe ijiya toto ti wa ni sepe fun awon olopa na, sugbon iwa ti ko ba oju mu ati ewo ni fun okunrin ni orilede yi lati ma gbe irun dada sori tabi ki won ya aworan si ara won.

O so si waju si wipe opolopo igba ni awon ti won ba gbe irun dada sori tabi ti won ya aworan sara yi man je omo egbe okunkun eleyi lo si maan fa ni opo igba ti awon olopa fi le da won duro tabi ki won fura si won.

Comments