Ko si iyato laarin Google ati Ifa - Ooni lo so be

Ooni ti Ife  Oba Enitan Ogunwusi ti se afihan to lagbara kan wipe ko si iyato ninu Ifa ati lilo ero ayelujara Google lati fi wadi nkan.

O se afihan yi nibi ipade kan ni ana ojo kewa osu kerin odun yi, o si so siwaju si wipe enikeni to ba ti gbiyanju lati wadi ohunkohun lori ero ayelujara Google, ti bere amoran lowo Ifa.

Comments