Ibanuje nla lo je nigba ti irohin iku oluko agba ni Unifasiti Ibadan ogbeni A.O. Subair to awon akorohin wa leti. Oluko agba na to ti kowe fi ise sile sugbon to sin gbe inu ile eko giga na ni iwadi fi han wipe o gba emi ara re ninu yara re to wa ni opopona Phillipson.
Awon to ba awon akorohin Sahara Reporters soro so wipe Oluko na lo ti ni irewesi okan lori opolopo awon nkan ti ko lo dede fun bo ti fe, ati wipe iyawo re ti gbe lo si ile ejo lati tu igbeyawo won ka ati bebe lo.
Won gbe oluko agba na lo si ile iwosan 'Jaja', to wa ninu ile iwe na, ki won to gbe lo si UCH nibiti ologbe na dake si.

Comments
Post a Comment