Ogbeni Nyesom Wike ti wole gege bi Gomina ipinle Rivers

Gomina ipinle Rivers, Ogbeni Nyesom Wike tun ti wole gege bi Gomina ipinle ni elekeji leyin eto idibo to waye ni ipinle na.

Ajo INEC lo se afihan ati atejade yi to si fi abajade na han wipe gbangba-gbangba oludije labe egbe oloselu PDP na lo gbe igba olubori ninu eto idibo na.

Eku orire o.

Comments