Ogbontarigi akowe ati olukotan ojogbon Oladejo Okediji ti ku. Baba omodoun mokandiladorun na lo fayesile ni nkan bi ago mewa ale ojo kewa osu kerin odun 2019.
Goke omo okunrin baba na lo se afihan na to si fi han wipe ko si aisan kankan to se baba na ki olojo to de. Ile re ni adugbo Mabolaje ni ilu Oyo ni baba na ku si.
Ara awon iwe ti baba na ko ki olojo to de ni Aja Lo Leru, Rere Run, Agbalagba Akan, Atoto Arere, Karin Kapo, Opa Agbeleka, Oga Ni Bukola, Sango, Iroyin Ayo, Binu Tiri and a play, Aajo Aje ati be be lo.

Comments
Post a Comment