Oserebirin Olabisi Monsurat eni ti gbogbo eyan mo si Bisket ti ku

Gbajugbaja oserebirin Olabisi Monsurat eni ti inagi re nje Bisket ni irohin to wa leti wipe o ti ku.

Gege bi iwadi ati atejade ti awon molebi ologbe na se, won fi han wipe iku arabirin na waye leyin ojo kewa ti oserebirin na bi omo tuntun. Ile iwosan kan ni ipinle Eko ni arabirin Bisket ku ni. Omo yi ni yo je omo kefa ti ologbe na bi.

Omo odun metadinladota ni ologbe na ki olojo to de. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin

Comments