Aworan oludije BBNaija Angel ati iyawo re Felicia

Ogbeni Ifiemi Angel Awotarigha eni ti gbogbo eyan mo si Angel ninu idije BBnaija lo se afihan aworan pelu iyawo re tuntun omo bibi orilede Canada Felicia.

O si dupe gidigidi lowo awon ololufe re fun ife ati ifowosowopo ti won fi fun won.

atejade to se ni yi ni ede geesi;

'See Ijaw people, thank you all for your love and support, I give you Mr. and Mrs. Angel Awotarigha.' 

Comments