Ijoba ipinle Katsina ti kilo wipe eni keni ti owo ba te fun esun ajinigbe, ajierangbe ati idigunjale o fi iku se ifaje
Gomina ipinle Katsina Aminu Masari ninu atejade kan to ba awon onirohin se ti fi idi re mule wipe iku ni ere ese fun enikeni ti owo ba ba fun esun ajinigbe, ajierangbe ati idigunjale.
Gomina na ati Masari ti fi ounte lu ofin na nibi ipade State Executive Council (SEC) to waye ni ipinle na ni ose to koja.
Gomina na ati Masari ti fi ounte lu ofin na nibi ipade State Executive Council (SEC) to waye ni ipinle na ni ose to koja.
Comments
Post a Comment