Aare orilede Egypt nigbakanri Mohammed Morsi ti ku

Aare orilede Egypt nigbakanri ni odun 2013, Mohammed Morsi ti awon ologun le kuro lori ijoba ni odun 2013 ti ku.

Gege bi irohin to to wa leti, Aare ana na lo so emi re nu nigba to subu lojiji ninu ile ejo Cairo Criminal Court ni ana ojo ketadinlogun odun 2019.


Comments