Awon agbofinro ti mu awon omo Nigeria marun latari wipe won fi ipa ba arabirin kan sun niseju Oko re ni orilede Ghana
Awon agbofinro ton mojuto ekun Tema ni orilede Ghana ti mu awon omo orilede Nigeria marun latari wipe won fi ipa ba arabirin kan lo niseju oko re.
Awon odaran na ni irohin fi to wa leti wipe won lo digunjale ni agbegbe na, ti won si fi ipa ba arabirin na sun nigbati won o ri owo fun won.
Owo palaba won segi nigba ti arabirin na ri ikan ninu awon odaran na ni adugbo na ni nkan bi ojo meji si ojo ti won se asemase na, ti won si fi olopa mu won.
Oga olopa Arko nigba ton ba awon akorohin soro, fi idi oro na mule, o si ti se ileri wipe awon odaran na o fi oju ba ile ejo lai-pe, lai jina.

Comments
Post a Comment