Awon omo ipinle Ondo ti ilekun ile Gomina Rotimi Akeredolu pa

Awon omobibi ipinle Ondo ti fi ehunu han si ise ijoba ipinle Ondo labe ise ijoba Gomina Rotimi Akeredolu latari wipe opopona na ilu na ti baje.

Awon odo ilu na to wa labe egbe  Ilaje Youths Congress (IYC), ati Ondo State Oil Producing Area Development Commission (OSOPADEC).

Awon asoju Gomina ti wa parowa siwon lati ni suru, wipe lai pe, awon o mojuto gbogbo edun okan ti won fi han.

Comments