Ijoba orilede Malaysia ti da awon omo orilede Nigeria pada nitori esun Jibiti ati egbe okunkun

 Awon omobibi orilede Nigeria ni ijoba orilede Malaysia ti dapada wale latari esun jibiti, egbe okunkun ati iwa ipanle. Nkan bi ago mewa-abo ni won bere si ko won.

Oga olopa ni ilu Malaysia Datuk Khairul Dzaimee Daud so wipe opolopo awon akegbe oun ni won farapa nigba ti won ko won.




Comments