Iyawo omo egbe agbaboolu Super Eagles Lucky Omeruo ti bi omo tuntun lanti-lanti

 Odomodekunrin agbaboolu Super Eagles, Ogbeni Lucky Omeruo ninu atejade ati afihan awon aworan kan to gbe sori ero ayelujara lo fi han wipe iyawo re Doreen ti bi omo tun-tun lanti-lanti.

O dupe lowo Olorun, o si ki Iyawo re ku orire.



Comments