O MA SE O! Odomodekunrin kan ZIGGY, jabo latori ile alaja merin ni agbegbe Lekki

 Ododmodekunrin, olorin takasufe kan ni irohin fi to wa leti wipe o jabo lati ori ile alaja merin kan to si so emi re nu ni agbegbe Lekki ni ipinle Eko.

Won ti gbe oku re lo si ite igbokusi, awon agbofinro si ti bere iwadi lori oro na.


Comments