Kayefi nla lo je nigbati irohin arakunrin kan ti won gbe lo si ile iwosan Aminu Teaching Hospital ni ipinle Kano to wa leti, arakunrin na ni iyawo re Hanan gbiyanju lati fi obe gun pa mole leyin osu meje ti won se igbeyawo.
Gege bi atejade kan ti ogbeni Mai Daraja Aliu se lori ero ayelujara facebook, so wipe awon toko-tiyawo na lo bere ija, ti esu si ta epo si oro na.
Won ti gbe Hana lo si ago olopa, ti arakunrin Hussain si n'gba itoju ni ile iwosan.
Atejade na ni yi ni ede geesi;

Comments
Post a Comment