Odomodekunrin kan ton se agunbaniro re ni ilu Ibadan, eni ti oruko re n'je Johnson Oyinlo ni irohin fi to wa leti wipe o gba emi ara re.
Ologbe Oyilo, eni to je omo bibi ilu Markurdi lo gba ekuru je lowo ebora ni ojo kerinla osu yi ni inu ile re ni ilu Ibadan.
Iwadi to peye ti wa n'lo lori oro na, won si ti gbe oku re lo si ite igbokusi kan to wa ni ilu Ibadan.

Comments
Post a Comment