Oga agba NURTW ni ipinle Eko MC Oluomo se ipade pelu Gomina Atlanta Georgia, ogbeni Brian Kemp

 Ninu atejade kan ti oga agba ajo NURTW, MC Oluomo se lori ero ayelujara instagram, o se afihan wipe Gomina orilede Atlanta ni Georgia lo fi iwe ranse si oun fun ipade ranpe.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

''Honorary invitation too me and my lovely son Ololade by the executive governor of Atlanta Georgia USA Brain Kemp and his Marty Kemp.
ALHAMDULLIA.

Comments