Ogbontarigi oloselu ni ipinle Kogi Ibrahim Ocheje ti ku

Ogbontarigi oloselu ati agba ninu egbe oloselu APC, ogbeni Ibrahim Ocheje ti ku.  Oloye Ocheje ni irohin fi to wa leti o jade laye leyin aisan ranpe  ni inu ile re to wa ni Ankpa.

Omo odun mokandiladorin ni ologbe na ki olojo to de. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments