Odomodebirin osere ati oludije ninu idije Big Brother Naija, BamBam ke gbajari lori ero ayelujara intagram latari wipe awon olopa gba eti aburo re kan ni agbegbe IITA ni ilu Ibadan. O so siwaju si wipe Awon agbofinro na gbiyanju lati yin ibon mo aburo re na, ti won si fi esun adigunjale kan.
Atejade na ni yi ni ede geesi;
Atejade na ni yi ni ede geesi;
Comments
Post a Comment