Oni Kete Jifin, Ola Kete Jifin, Se Kete nikan lo wa lofin ni? Olusoaguntan Fatoyinbo VS Busola Dakolo
Latari afihan ati atejade amohun-maworan ti Arabirin Busola Dakolo ba awon onirohin se, nipa wipe ojise Olorun ati oludasile ijo COZA ogbeni Fatoyinbo fi ipa ba oun lo.
Orisiri iwadi lo ti bere lori oro na ti Ojise olorun na si ti se atejade kan lori ero ayelujara instagramu re wipe iro nla pata-pata gba ni, o so siwaju si wipe igbiyanju ni lati ba oruko oun je, ati lati ri wipe ise iranse oun di yepere loju awon eyan.
O so siwaju si wipe igbiyanju esu ni lati gbe ogun ti iyin rere Jesu Kristi, o si so wipe oun ti setan lati gbe arabirin Busola Dakolo lo si ile ejo.
Bakana, opopolopo awon eyan ti pinu lati wadi oro na fini-fini, ti opolopo awon eyan lori ero ayelujara si je ko ye arabirin Busola wipe awon wa leyin re digbi-digbi.

Comments
Post a Comment