Ijamba oko ofurufu kan ti ko ba da emi opolopo awon ero ni egbodo ni ori ko yo nigbati oko ofurufu Air Peace si ona to si mu ori wo igbo lo.
Adupe wipe ko si enikankan to farapa ninu isele ijamba oko ofurufu na. Iwadi to peye ti wa n'lo lori isele na lati fi idi isele na mule.
Comments
Post a Comment