Amotekun; Igbakeji Aare Yemi Osinbajo, Oga olopa ati awon Gomina kookan ti fowo si wipe ki Amotekun fi idi mule


Ninu atejade kan ti agbenuso fun Igbakeji Aare Yemi Osinbajo, ogbeni Laolu Akande se lori ero ayelujara twitter, O fi han, o si fi idi re mule wipe Igbakeji Aare, Oga olopa ati awon Gomina kookan ti fi owo si, ti won si ti fi ounte lu wipe ki Amotekun te siwaju.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

"News Flash: FG, Southwest Governors agree on Amotekun.
VP Osinbajo after presiding over National Economic Council, also met with Southwest Governors to sort out the Amotekun issues. The President who is away asked the VP to host the meeting. The AGF & IGP were also in attendance & everyone at the meeting agreed Amotekun should go on."

Comments